最新搜索

See Me See God (SMSG) - Barry Jhay.lrc

LRC歌词 下载
[00:00.000] 作曲 : Oluwakayode Junior Balogun
[00:00.030] 制作人 : SMART P CLASSIC
[00:00.060]Ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
[00:03.390]Ọrọ mi d'akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
[00:07.870]Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn
[00:11.280]Ẹni j'alangba n tutu, a kó warapa
[00:16.940]Oh-ah, oh-ah-ah-ah
[00:21.730]Yeah, ay-ya-ay, ah-ah, ah
[00:26.720]Oh-wa, oh, wa-wa-wa
[00:30.690](Nobody's perfect)
[00:32.380]Yea, k'iku ma-ma pa awọn to gbe mi s'ori bi gele
[00:39.420]Ki ibanujẹ jina si wa rere, tefe-tefe
[00:48.400]K'iku ma p'ọta mi, ko le r'iran wo
[00:54.260](O ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah)
[00:59.430]Ki'ku ma p'ọta mi, ko le r'iran wo
[01:03.040](Mo ṣi n m'ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese Lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na)
[01:08.500]If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
[01:13.260]Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
[01:17.310]Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
[01:25.210]See me, see God o, abi emi naa kọ
[01:28.170]Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
[01:32.570]Ṣe you dey see level o?
[01:34.860]Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yеah, tẹti mọ ọ, ye
[01:40.910]Ye, as I dey find wеtin I go chop, ooh-iy
[01:46.760]Make I no jam wetin go chop me
[01:49.740]Olúwa lo gbe (Yea-yea), lo gbe mi s'oke
[01:54.240]Emi ko le ṣ'ai ṣope
[01:58.040]See me, see God o, abi emi naa kọ
[02:02.590]Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
[02:07.340]Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
[02:09.610]Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah)
[02:15.350]Yeah, o l'oju ọmọ to damọ
[02:17.340]If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
[02:21.870]Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
[02:25.950]Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
[02:33.800]See me, see God o, abi emi naa kọ
[02:36.850]Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
[02:41.420]Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
[02:43.940]Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah)
[02:48.970]Yeah, o l'oju ọmọ to damọ
[02:53.140]Sunshine
[03:07.857] 音频工程师 : Dibstunez
文本歌词
作曲 : Oluwakayode Junior Balogun
制作人 : SMART P CLASSIC
Ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
Ọrọ mi d'akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn
Ẹni j'alangba n tutu, a kó warapa
Oh-ah, oh-ah-ah-ah
Yeah, ay-ya-ay, ah-ah, ah
Oh-wa, oh, wa-wa-wa
(Nobody's perfect)
Yea, k'iku ma-ma pa awọn to gbe mi s'ori bi gele
Ki ibanujẹ jina si wa rere, tefe-tefe
K'iku ma p'ọta mi, ko le r'iran wo
(O ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah)
Ki'ku ma p'ọta mi, ko le r'iran wo
(Mo ṣi n m'ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese Lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na)
If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o?
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yеah, tẹti mọ ọ, ye
Ye, as I dey find wеtin I go chop, ooh-iy
Make I no jam wetin go chop me
Olúwa lo gbe (Yea-yea), lo gbe mi s'oke
Emi ko le ṣ'ai ṣope
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah)
Yeah, o l'oju ọmọ to damọ
If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah)
Yeah, o l'oju ọmọ to damọ
Sunshine
音频工程师 : Dibstunez

相关歌曲